Aldehyde dehydrogenase 16 family, member A1 tí a tún mọ̀ sí ALDH16A1 jẹ́ aldehyde dehydrogenase gene.
Àwọn ìyípadà nínú SPG21 (ACP33/maspardin) gene ní ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú mast syndrome, tí ó jẹ́ irú spastic paraplegia. Protein tí ó ń kóòddù fún SPG21 gene ní ìrẹ́pọ̀ pẹ̀lú ALDH16A1 enzyme.[1]