Abass Àkàndé Òbésèré | |
---|---|
Abass Akande | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Abass Akande |
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi | Omo Rapala, Papa Tosibe, Sidophobia |
Ọjọ́ìbí | January 28 1965 (ọmọ ọdún 59–60) Ibadan, Oyo State, Nigeria |
Irú orin | |
Occupation(s) | Singer-songwriter |
Instruments | Vocals |
Years active | 1981–present |
Labels |
Abass Àkàndé Òbésèré tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Ọmọ Rápálá (ojoibi 28 January ọdún 1965) jẹ́ gbajúmọ̀ olórin Fújì ọmọ bíbí ìlú Ìbàdàn ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ láti orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ìràwọ̀ Òbésèré tán nípa orin alùfàǹṣá Fújì tí ó máa ń kọ. Orin Àṣàkáṣà ní ó pọ̀jù nínú àwọn orin Fújì rẹ̀, kódà, ó pe ara rẹ̀ ní Ọba Àṣàkáṣà nínú àwo rẹ̀ kan.[3] [4]