Adamu adamu

Mallam

Adamu Adamu
Mínísítà fún ètò ẹ̀kọ́
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
11 November 2015
ÀàrẹMuhammadu Buhari
AsíwájúIbrahim Shekarau àtiNyesom Wike (ni ọdún 2014)
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí25 Oṣù Kàrún 1954 (1954-05-25) (ọmọ ọdún 70)
Azare, àríwá Nàìjíríà,
British Nigeria
(now Azare, Katagum, Bauchi State, Nigeria)
Alma materAhmadu Bello University
Columbia University

Mallam Adamu Adamu CON[1] (tí a bí ní 25 May 1954) jẹ́ Ọ̀mọ̀wé onisiro àti Oniroyin ní Naijiria, òun ní Mínísítà fún ètò ẹ̀kọ́ lowolowo ní Naijiria .[2][3][4][5]

Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A bí Adamu ni ọjọ́ karundilogbon oṣù karun(25 May) ọdun 1954, in Azare.[6] Ó gba àmì ẹyẹ nínú ìmò ìṣirò ní Yunifásitì ti Ahmadu Bello, Zaria. Ó tún padà gba àmì ẹyẹ master's degree nínú ìmò ìròyìn ni School of Journalism ti Yunifásitì Columbia[7][8] Ó le sọ èdè púpò, èdè bi Hausa, Inglisi, Persian, Arabic àti French.[7] Ó wá láti ìpínlè Bauchi, Nàìjíríà.[9]

  1. "FULL LIST: Okonjo-Iweala, Abba Kyari... FG nominates 437 persons for national honours". TheCable (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-10-02. Retrieved 2022-10-13. 
  2. "Jubilation at Education Ministry as Adamu takes over". dailypost.ng. Daily Post. Retrieved 3 October 2017. 
  3. "ASUU: FG sets up visitation panels, whitepaper committees". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-02-18. Retrieved 2022-02-22. 
  4. "FG will continue to invest big in education, says Minister". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-03-13. Archived from the original on 21 June 2022. Retrieved 2022-06-21. 
  5. "What changed Mallam Adamu Adamu’s position on Asuu - was it office? The Nation Newspaper" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-03-20. Retrieved 2022-06-21. 
  6. "Profile of Minister of Education, Mallam Adamu Adamu". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-08-21. Retrieved 2020-02-07. 
  7. 7.0 7.1 "Executives-Ministry of Education". nigeria.gov.ng. Federal Government of Nigeria. Archived from the original on 3 October 2017. Retrieved 3 October 2017. 
  8. "FOR THE RECORD: Official citations of Buhari’s ministers, SGF - Premium Times Nigeria" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-08-21. Retrieved 2022-06-21. 
  9. "Biography of Adamu Adamu". biography.hi7.co. Retrieved 2022-03-07.