Ori Ire | |
---|---|
Country | ![]() |
State | Oyo State |
Government | |
• Local Government Chairman and the Head of the Local Government Council | Olateju Michael Alabi (PDP) |
Time zone | UTC+1 (WAT) |
Agbègbè Ìjọba Ibilẹ jẹ́ agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Nàìjíríà. Olú-ìlú rẹ̀ wà ní ìlú ìkòyí.
Ó ní agbègbè 2,116km² àti iye ènìyàn tí ó tó 150,628 ní ètò ìkà ènìyàn tí ó wà yé ni ọdún 2006.
Àmì ọ̀rọ̀ ìfilẹ́tà rán ṣẹ́ agbègbè ní 210. Ó ní ìwọ̀n-ilẹ̀ tó tó 2,116 2.[1]
Iwòn ìgbóná tí ìkòyí-ilé ga púpò, pẹ̀lú oṣù kẹ́ta tí ó mú oru jùlọ, pẹ̀lú ìwọ̀n 91°F.[2][3]
|url-status=
ignored (help)