Abdul Ahmed Ningi | |
---|---|
![]() Senato Abdul Ningi níbi ìpàdé ilé ìgbìmò asòfin àgbà | |
Igbákejì olórí àwọn tó pọ̀jùlọ ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga Ọjọ́ keje Oṣù kẹfà Ọdún 2011 | |
Ààrẹ | Goodluck Ebele Jonathan |
Asíwájú | Mohammed A. Muhammed |
Aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin kékeré | |
In office Ọjọ́ kẹjọ Oṣù kẹfà Ọdún 1999 – Ọjọ́ kẹfà Oṣù kẹfà Ọdún 2011 | |
Asíwájú | Wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ da sílẹ̀ |
Arọ́pò | Abdulrazaq Zaki |
Chairman of the House Committee on Police Affairs | |
In office Ọjọ́ kejìlá Oṣù kẹfà Ọdún 2007 – Ọjọ́ kẹfà Oṣù kẹfà Ọdún 2011 | |
olórí àwọn tó pọ̀jùlọ ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà | |
In office Ọjọ́ kẹwá Oṣù kẹfà Ọdún 2003 – Ọjọ́ kọkànlá Oṣù kẹfà Ọdún 2007 | |
Alága tí House Committee fún àwọn ohun alùmọ́nì | |
In office Ọjọ́ kọkànlá Oṣù kẹfà Ọdún 2002 – Ọjọ́ kẹsán Oṣù kẹfà Ọdún 2003 | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Abdul Ahmed Ningi 20 Oṣù Kẹrin 1960 Ningi, Bauchi, Nigeria. |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People's Democratic Party (PDP) |
Residence | Ningi, Bauchi |
Alma mater | Ahmadu Bello University (BSc.) |
Profession | Oṣìṣẹ́ ìjọba |
Website | AbdulNingi.com |
Ahmed Abdul Ningi jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú Àárín Ìpínlẹ̀ Bauchi ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin lẹ́yìn tí ó wọlé látàrí ètò ìdìbò ti oṣù kẹrin ọdún 2011 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[1][2][3][4]