Áìshà Bùhárí | |
---|---|
Assumed role 29 May 2015 | |
Asíwájú | Patience Jonathan |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Aisha Halilu 17 Oṣù Kejì 1971[1][2][3] former fist Adamawa, Nigeria |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | APC |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Muhammadu Buhari (m. 1989) [1][4] |
Àwọn ọmọ | 5
Aisha Buhari
Halima Buhari Yusuf Buhari Zarah Buhari Amina Buhari |
Relatives | Muhammadu Ribadu (grandfather) |
Residence | Aso Villa |
Profession | Businesswoman |
Aisha Buhari (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kejì ọdún 1971)[3]) jẹ́ Obìnrin Àkọ́kọ́ Lorílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti Ìyàwó Ààrẹ Muhammadu Buhari , Ààrẹ ana orílẹ̀ ède Nàìjíríà tí sa a re dopin ni ojo kokan din logbon osu kefa odun 2023. Ààrẹ Buhari gbàpò lọ́wọ́ Ààrẹ, Goodluck Jonathan lọ́dún 2015, bẹ́ẹ̀ náà ó tún borí Igbákejì Ààrẹ nígbà ìṣèjọba Olúṣẹ́gun Ọbásanjọ́ , Atiku Abubakar nínú ìdìbò tó wáyé lọ́dún 2019 fún sáà Elékejì. Áìshà jẹ́ aṣerunlóge, aṣaralóge àti oǹkọ̀wé.[5][6][7]
Wọ́n Áìshà bí ní Ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kejì ọdún 19711[8][9][10] ní ìpínlẹ̀ Adámáwá, lápá àríwá orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[11] Bàbá rẹ̀ àgbà Alhaji Muhammadu Ribadu ní mínísítà ààbò àkókò fún orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. [12] Akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ ẹ̀rọ ní bàbá Áìshà Buhari, Màmá rẹ̀ sìn jẹ́ ẹbí Ankali, gbajúgbajà àgbẹ̀ tí gbogbo ènìyàn mọ̀. Áìshà Bùhárí kàwé àkóbẹ̀rẹ̀ àti gírámà ní ìpínlẹ̀ Adamawa.[13] Lọ́jọ́ kejì, oṣù Kejìlá ọdún 1989, Áìshà fẹ́ Ààrẹ Muhammadu Buhari lọ́kọ,[1][4][14] ẹni tí ó ti bímọ márùn-ún pẹ̀lú àkọ́fẹ́ ìyàwó rẹ̀, Safinatu Yusuf. Áìshà àti Ààrẹ Muhammadu Buhari bímọ márùn-ún àti ọmọ ọmọ kan ṣoṣo fún ara wọn.[15]
<ref>
tag; no text was provided for refs named guardian
<ref>
tag; no text was provided for refs named ibtimes
|url-status=
ignored (help)
|url-status=
ignored (help)