Ameyo Adadevoh | |
---|---|
Ìbí | Ameyo Stella Adadevoh 27 Oṣù Kẹ̀wá 1956 Èkó, Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà |
Aláìsí | 19 August 2014 Èkó , Nàìjíríà | (ọmọ ọdún 57)
Ọmọ orílẹ̀-èdè | ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà |
Ilé-ẹ̀kọ́ | First Consultant Medical Centre |
Ibi ẹ̀kọ́ | University of Lagos (MBBS) University of London (Endocrinology) |
Ameyo Stella Adadevoh (tí a bí ní ọjọ́ Kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù Kẹ̀wá ọdún 1956 tí ó sì fi ayé sílè ní ọjọ́ kàndínlọ́gún oṣù kẹjọ ọdún 2014) jẹ́ onímọ̀ ìṣẹ́gun òyìnbó ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Àwọn ènìyàn ma ń ròyìn rẹ̀ fún ipa tí ó kó nínú mímú owó ààrùn Ebola Virus balẹ̀ ní Nàìjíríà nípa mímú ẹni àkọ́kọ́ tí ó kọ́kọ́ ní ààrùn náà, Patrick Sawyer, sí ibi ìpamọ́ bí ó tilè jẹ́ wípé àwọn ìjọba Làìbéríà tako fí fi Patrick sí ìpamọ́.[1][2][3] Ní ọjọ́ kẹrin oṣù kẹjọ ọdún 2014, ìwádìí àyẹ̀wò fihan pé ààrùn Ebola wà lára rẹ̀, àwọn onímọ̀ ìṣẹ́gun sì bẹ̀rẹ̀ ìtójú fún lé sẹ̀kẹ́sẹ̀.[4] Ṣùgbọ́n Adadevoh fi ayé sílè ní ọ̀sán ọjọ́ kan dínlógún oṣù kẹjọ ọdún 2014.[5][1] Ó fi ọkọ rẹ̀, Afolabi àti ọmọ rẹ̀, Bankole sílè sáyé.
|url-status=
ignored (help)
|url-status=
ignored (help)