Amitabh Bhattacharjee | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 15 Oṣù Kẹjọ 1973 New Delhi, New Delhi, India |
Orílẹ̀-èdè | Indian |
Iṣẹ́ | Actor |
Website | [1] |
Amitabh Bhattacharjee (ọjọ́ìbí 15 August 1973)[1] ni òṣeré ará India tó ún ṣeré nínú àwọn fílmù èdè Bengali àti Hindi.[2] Ó dàgbà ní Delhi. Ó kọ́kọ́ ṣeré nínú fílmù Rasta, tí Bratya Basu ṣe olùdarí, pẹ̀lú Mithun Chakraborty.[3] Ó ti kópa nínú ọ̀pọ̀ fílµu lédè Bengali àti Hindi.[4][5]
|url-status=
ignored (help)