Anna Banner | |
---|---|
Banner ni odun 2014 | |
Ọjọ́ìbí | Anna Ebiere Banner 18 Osu keji 1995[1] |
Iṣẹ́ | Osere, afewasise |
Gbajúmọ̀ fún | Miss World 2013 |
Awards | Most Beautiful Girl In Nigeria 2013 |
Anna Ebiere Banner (tí a bí ní 18 Oṣù Keèjì 1995) jẹ́ olúborí ìdíje ẹ́wà at̀i òṣèré. Ní ọdún 2013, wọ́n de ládé Ọmọbìnrin tó rẹwà jùlọ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà,[2] ó sì ṣojú Nàìjíríà níbi ìdíje ẹ́wà àgbáyé ní ọduń 2013 bákan náà. Ó rí yíyán fún ipò olùrànlọ́wọ́ pàtàkì sí Gomina Henry Dickson lórí Àṣà àti Ìrìnrìn-àjò, nípasẹ̀ ìjọba rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi Ọmọbìnrin tó rẹwà jùlọ ní Nàìjíríà ní ọdún 2012.[3] Ní ọdún 2014, ó ṣe ìṣàfihàn eré àk|ọ́kọ́ rẹ̀ nínu Super Story.[4]