Apaadi

Apaadi
AdaríAbiodun Olanrewaju
Olùgbékalẹ̀Funke Akindele
Àwọn òṣèréFunke Akindele
Femi Adebayo
Yinka Quadri
Taiwo Hassan
Adebayo Salami
Ronke Odusanya
Peju Ogunmola
Opeyemi Aiyeola
Sola Kosoko
Moji Olaiya
Lola Margret
Peter Fatomilola
Ilé-iṣẹ́ fíìmùScene One Productions
OlùpínOlasco Films Nig. Ltd.
Orílẹ̀-èdèNigeria
ÈdèYoruba

Apaadi jẹ́ fíìmù Yorùbá ti ilẹ̀ ọdún 2009. Ó jẹ́ fíìmù adá-lórí-ìtàn-gidi, èyí tí Funke Akindele máa kọ́kọ́ ṣe, òun náà sì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn akópa eré náà. Africa Movie Academy Awards yan fíìmù náà ní ọdún 2009, fún fíìmù tó dára jù lọ ní èdè Afrika àti ìṣeyege nínú asọ eré. Wọ́n sì yan Femi Adebayo fún òṣèrékùnrin tó dára jù, fún ìkópa rẹ̀ nínú eré náà.[1]

Àwọn àmì-ẹ̀ye àti yíyàn fún àmì-ẹ̀yẹ

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Ọdún Àmì-ẹ̀yẹ Ìsọ̀rí Olùgbà Èsì Ìtọ́ka
2009 Africa Movie Academy Awards Best Film in African Language Apaadi Wọ́n pèé [2]
Achievement in Costume Apaadi Wọ́n pèé
Best Supporting Actor Femi Adebayo Wọ́n pèé

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]