Agharese Emokpae (tí wọ́n bí ní January 13, 1988) tí wọ́n mọ̀ sí A'rese jẹ́ òṣèrébìnrin, akọrin àti òǹkàtàn ọmọ Nàìjíríà. Ó di gbajúmọ̀ nígbà tí ó kópa nínú fíìmù Bolanle Austen-Peters' Terra Kulture, tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Wakaa: The Musical, èyí sì mu kópa nínú ìdíje The Voice Nigeria, tó sì jáwé olúborí.[1] Ní ọdún 2017 ó di gbajúgbajà fún ìkópa rẹ̀ bí i Senami Minasu nínú fíìmù Africa Magic tí àkọ́lé rẹ̀ ń jé Jemeji. Lọ́dún yẹn náà ni ó ṣe àgbéjáde orin rẹ̀ àkọ́kọ́, tó pè ní "Uwe No".[2]
Inú iṣẹ́-ọnà ni wọ́n bí A'rese sí. Bàbá-bàbá rẹ̀ ni gbajúgbajà ayàwòrán àti agbẹ́gilére tí orúkọ rè ń jẹ́ Erhabor Emokpae.
A'rese lọ ilé-ìwé Washington and Lee University níbi tí ó tí kúndùn orin kíkọ àti ijó. Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè Bachelor of Arts nínú ẹ̀kọ́ Visual Art, tó sì dojú lé Printmaking. Lẹ́yìn tí ó kópa gẹ́gẹ́ bí i "Velma Kelly" nínú fíìmù Broadway musical Chicago, ó pinnu láti tẹ̀síwájú nínú iṣẹ́ eré-ṣíṣe.[3] Láti ìgbà tó kẹ́kọ̀ọ́ jáde ní ọdún 2010 ni ó ti mú iṣẹ́ yìí gẹ́gẹ́ bí èyí tó yàn.
Emokpae bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ ní Chicago, Illinois[4]. Púpọl lára àwọn ẹ̀dá-ìtàn tó ṣe ní tíátà náà ni The Fairy Godmama nínú fíìmù The Other Cinderella[5] àti Mya nínú One Name Only.[6] Lẹ́yìn tó ṣiṣẹ́ níbẹ̀ fún ọdún mẹ́ta, ó pinnu láti kó wá́ sí Èkó, ní Nàìjíríà láti wà ṣe iṣẹ̀ náà ni pẹrẹu.
Ní ọdún 2014, ó kópa nínú àgbéjáde BAP, ìyẹn Saro: the Musical 2.[7] Ó tún farahàn gẹ́gẹ́ bí i Kike Johnson nínú fíìmù àwọn BAP/Terra Kulture stable, ìyẹn Wakaa: The Musical[8].
Ní ọdún 2016, Emokpae gbìyànjú láti kópa nínú ètò The Voice Nigeria. Lára àwọn orin tó kọ ní Skyfall àti Hallelujah. Ó gbégbá orókè pẹ̀lú Chike.[9]
Lẹ́yìn àṣeyọrí yìí, Emokpae tọwọ́ bọ̀wé pẹ̀lú Universal Music Group; níbi tí ó ti ṣá̀gbéjáde orin rẹ̀ àkọ́kọ́, ìyẹn Uwe No.[10]
Ní ọdún 2017, ó kópa nínú fíìmù Jemeji gẹ́gẹ́ bí i Senami Minasu. Ó sì tún kópa nínú fíìmù EbonyLife TV kan, ìyẹn "MMM".[11]
Year | Title | Network | Role | Notes |
---|---|---|---|---|
2016 | The Voice Nigeria | Africa Magic | Self | Reality Show |
Babysitting Ejiro | Kemi | Television movie | ||
2016-2017 | Tinsel | Bisola | Unknown # of episodes | |
2017-2018 | Jemeji | Senami Minasu | 260 episodes | |
2021 | M.M.M. | LacedUp Productions | Marion | Web Series |
Year | Show | Role | Notes |
---|---|---|---|
2012 | The Marvin Gaye Story | Mary Wells/Ensemble | Black Ensemble Theater; Chicago, IL |
One Name Only | Mya | ||
The Other Cinderella | Fairy Godmamma | ||
2013 | Once Upon A People | The Storyteller | |
She Kills Monsters | Vera (u/s) | Buzz22 Chicago at Steppenwolf; Chicago, IL | |
2014-2015 | Saro: The Musical 2 | Rume | BAP Productions/Terra Kulture |
2015 | Wakaa: The Musical | Kike Johnson |
Year | Song Title | Artist | Album |
---|---|---|---|
2017 | "Uwe No" | A'rese ft. LadiPoe | Uwe No - Single |
2018 | "Beautiful" | A'rese | Beautiful - Single |
Year | Song Title | Artist | Album |
---|---|---|---|
2017 | "Out Of My League" | Dominic Neill ft. A'rese | Out Of My League |
"#WCW" | Kalen Lumiere ft. A'rese | Realistic Love | |
"Birds 'n' Bees" |
Year | Award | Category | Film | Result | Ref |
---|---|---|---|---|---|
2019 | Best of Nollywood Awards | Best Actress in a Lead role –English | Unbreakable | Wọ́n pèé | [12] |
<ref>
tag; no text was provided for refs named :02
|url-status=
ignored (help)