Asher Blinkoff | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 23 Oṣù Kọkànlá 2008 Aston, Pennsylvania, U.S. |
Orílẹ̀-èdè | American |
Iṣẹ́ | Actor, voice actor |
Ìgbà iṣẹ́ | 2012-present |
Notable work | Hotel Transylvania 2 Hotel Transylvania 3: Summer Vacation |
Parent(s) | Marion Blinkoff (mother) Saul Blinkoff (father) |
Ẹbí | Meira Blinkoff (sister) |
Asher Blinkoff tí wọ́n bí ní ọjọ́ Kẹtalélógún oṣù Kọkànlá ọdún 2008, òṣèrémọdé ọkùnrin tí ó di ìlú-mòọ́ká fún ipa rẹ̀ tí ó kó nínú eré Hotel Transylvania film franchise gẹ́gẹ́ bí ẹ̀dá ìtàn Dennis fún ilé-iṣẹ́ Columbia Picturesàti Sony Pictures Animation.
Asher Blinkoff jẹ́ ọmọ bíbí Marion àti Saul Blinkoff.[1] Blinkoff di gbajú-gbajà látàrí ipa rẹ̀ tí ó kó nínú eré Hotel Transylvania 2 nígbà tí ó wà ní déédé ọmọ ọdún Mẹ́fà. [2]
Blinkoff ní ẹ̀gbọ́n obìnrin tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ "Meira" tí òun náà jẹ́.òṣèré pẹ̀lú [3]
Ọdún | Àkọ́lé | Ioa tí ó kó | Notes |
---|---|---|---|
2016 | The Jungle Book | Young Wolf | Voice |
Ọdún | Àkọ́lé | Ipa tí ó kó | Notes |
---|---|---|---|
2012 | Wake-up Call (For Him) | Himself | Short film |
Wake-up Call (For Her) | Baby | ||
2015 | Taking Flight | Tony | |
Hotel Transylvania 2 | Dennis | ||
2016 | Bling | Minitar | |
Sing | Piglet | Uncredited | |
2017 | Puppy! | Dennis | Short film |
2018 | Hotel Transylvania 3: Summer Vacation | ||
2021 | Hotel Transylvania 4 |