Taxonomy not available for Asimina; please create it automated assistant
Asimina parviflora | |
---|---|
![]() | |
Ipò ìdasí | |
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ edit ] | |
Irú: | Template:Taxonomy/AsiminaA. parviflora
|
Ìfúnlórúkọ méjì | |
Template:Taxonomy/AsiminaAsimina parviflora (Michaux) Dunal
|
Asimina parviflora, ti o tun n jẹ smallflower pawpaw, ni ó jẹ́ igi eléso kékeré tí ó jẹ́ ìkan lára custard apple
Asimina parviflora | |
---|---|
![]() | |
Scientific classification ![]() | |
Kingdom: | Plantae |
Clade: | Tracheophytes |
Clade: | Angiosperms |
Clade: | Magnoliids |
Order: | Magnoliales |
Family: | Annonaceae |
Genus: | Asimina |
Species: | A. parviflora
|
Binomial name | |
Asimina parviflora (Michaux) Dunal
|
A le ri igi yi ni apá Guusu ìlà oòrùn Orílẹ̀ èdè America, láàárín ìlú Texas sí Virginia . Igi yi saba ma n hu si àgbègbè tí iyanrìn bá pọ̀ sí jùlọ àti ibi tí àwọn igi gbígbẹ bá wà. [2]
Igi èso Asimina parviflora ní omi aró maroon, tí àwọn òdòdó orí rẹ̀ sì ma ń nípọn páá pàá jùlọ nígbà ti òjò bá ṣẹ̀ṣẹ̀ bẹ̀rẹ̀ nínú ọduń. Ó ma ń so èso tí ó fara jọ èso ìbẹ́pẹ tí a lè jẹ, ṣugbọn èso rẹ kéré ju ti ìbẹ́pẹ lọ.
Àwọn eruku òdòdó rẹ̀ ma ń fọ́nká sílẹ̀ lásìkò tí ó bá ń gbaradì láti so èso. A tún lè ri ní apá gúúsù àwọn ìlú tí a ti mẹ́nu bà lókè yí jù àwọn ìbẹ́pẹ gangan lọ. Gẹ́gẹ́ bí a ti sọ, igi èso parviflora kìí fi bẹ́ẹ̀ ga púpọ̀, wọn kìí ga ju ìwọn ẹsẹ̀ bàtà méta lọ, díẹ̀ lára wọn ni ó ma ń ga ju ẹgbẹ́ lo. Àwọn òdòdó rẹ̀ kíí sábà fẹ̀ ju ìwọ̀n sẹ̀ntímítà méjì lọ. Òdòdó rẹ̀ ni ó kọ́kọ́ ma ń bẹ̀rẹ̀ pèlú àwọ̀ omi búráùn, yóò sì tún di aláwọ̀ ewé nígbà tí ó bá ń dàgbà, yóò sì yí padà sí àwọ̀ màrúnùn nígbà tí ó bá ti gbó tán.
Àwọn ewé jẹ́ aláwọ̀ ewé dúdú nígbàgbogbo, àti dídán ní sojurigindin. [3]
A. parviflora hybridizes ni imurasilẹ pẹlu A. triloba lati ṣe agbekalẹ Asimina ×piedmontana .
<ref>
tag; name "iucn" defined multiple times with different content