Atonye Nyingifa

Atonye Nyingifa
No. 21 – Porta XI Ensino
PositionPower forward
LeagueLFB
Personal information
Born8 Oṣù Kejìlá 1990 (1990-12-08) (ọmọ ọdún 34)
Torrance, United States
NationalityAmerican / Nigerian
Listed height1.83 m (6 ft 0 in)
Career information
High schoolRedondo Union High School
(Redondo Beach, California)
CollegeUCLA (2014)
NBA draft2014 / Undrafted

Atonye Nyingifa (tí wọ́n bí ní 8 December 1990) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù alájùsáwọ̀n ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó tan mọ́ ìlú America. Ẹgbẹ́ Porta XI Ensino àti Nigerian national team ni ó ń gba bọ́ọ̀lù náà fún.[1]

Ó kópa nínú ìdíje 2017 Women's Afrobasket.[2]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. FIBA profile
  2. 2017 Women's Afrobasket profile