' | |
---|---|
Adarí | Tunde Kelani |
Òǹkọ̀wé | Bola Anike Obot |
Àwọn òṣèré |
|
Déètì àgbéjáde |
|
Àkókò | 100min |
Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Èdè | Yoruba |
Ayọ Ni Mọ Fẹ jẹ́h fíìmù eré-oníṣe ti ilẹ̀ Yorùbá, èyí ti Tunde Kelani jẹ́ olùarí fún, tí ó sì jáde ní ọdún 1994 láti ọwọ́ Mainframe Films and Television Productions.[1][2]