Aïcha Macky | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Aïcha Elhadj Macky 8 Oṣù Kínní 1982 Niger |
Orílẹ̀-èdè | Nigerien |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Gaston Berger University |
Iṣẹ́ | Director |
Ìgbà iṣẹ́ | 2011–present |
Aïcha Elhadj Macky (8 Oṣù Kínní Ọdún 1982) jẹ́ olùdarí eré àti olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè Nìjẹ̀r. Ó tún jẹ́ onímọ̀ nípa àwùjọ.[1] Ó gbajúmọ̀ jùlọ fún dídarí eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ The Fruitless Tree.[2]