Bangubangu je eya kan ni Afrika.
Èdè wọn ni wọn ń pè ni Bantu, wọ́n tún lè pè é ni kiban gubangu, èdè,
yìí pin si ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta (500) ede méjìlá nínú èdè bantu ni ògọ̀ọ̀rọ̀
àwọn ènìyàn tó lè ni mílíọ́ọ́nù márùn-ún ń sọ, lára àwọn tí ó ń sọ
èdè Bantu ni Rundi, Rwanda, Shona, Xhosa àti Zulu, Swalili. Èdè Olóhùn ni
èdè yìí fún àpẹẹrẹ ní Zulu, íyàngà túmọ̀ si dókítà, nígbà tí ìyángá
túmọ sí òṣùpá.
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |