Barney Simon | |
---|---|
Ọjọ́ ìbí | 13 Oṣù Kẹrin 1932 |
Ọjọ́ aláìsí | 30 June 1995 (aged 63) |
Iṣẹ́ | Playwright, director |
Èdè | English |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | South African |
Notable works | Woza Albert! |
Barney Simon (ọjó kẹtàlá oṣù Ìgbé ọdún 1932 – si ọgbọn ọjó oṣù okundu ọdún 1995)[1] kí a má ṣe dà á pọ mọ́ Jacaranda FM radio DJ Barney Simon. Barney Simon jẹ́ òǹkọ̀wé ilẹ̀ South African àti olùdarí fíìmù. Ìlú Johannesburg ní SOuth Africa ni wọ́n bi sí, ibẹ̀ sì ni ó kú sí.[2]
Simon ṣe àwárí ìfẹ́ rè fún iṣẹ́ tíátà lásìkò tí ó ń ṣiṣẹ́ pẹ̀lú Joan Littlewood ní London, ní ọdún 1950. Lẹ́yìn tó padà sí Johannesburg, ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí i òǹkọ̀wé fún ilé-iṣẹ́ ìpolówó-ọjà kan, lásìkò tó ń ṣịṣẹ́ olùdarí fún fíìmù. Ki o tó ṣí ọjà náà, o n ṣe eré ìtàgé nibi gbogbo ti ọ bá ti ni ore ọfẹ lati ṣe: in warehouses and shantytowns, storefronts and back yards, including Athol Fugard's The Blood Knot (1961). Simon spent a year (1969–70) in New York City, where he introduced South African plays to an American audience and edited the journal New American Review.