Brotherhood jẹ́ fíìmù Nigeria tí ó dá lórí ẹ̀ṣẹ̀ àti jàgídíjàgan tí Jáde Osiberu ṣe tí àwọn tó jáde nínú rẹ̀ sì pẹ̀lú Tobi Bakre, Boma Akpore, Falz, Basketmouth, Sam Dede, Ronke Oshodi Oke, Toni Tones, Zubby Micheal, Mr Macaroni àti àwọn òṣèré míràn lóríṣiríṣi.[1][2] Fíìmù náà jáde ní àwọn sinimá ní ilẹ̀ adúláwò ní 23, Oṣù Kẹ̀sán ọdún 2022. Ó sì jáde ní àwọn orílẹ̀ èdè ní àsìkò kan náà. Àwọn orílẹ̀ èdè yìí pẹ̀lú Nigeria, Cameroon, Benin Republic, Burkina Faso, Togo, Niger Republic, Senegal, Congo, Rwanda, Gabon, Guinea, àti Madagascar.[3]
a