Alternative names | Brodet, brodetto |
---|---|
Type | Stew |
Course | Main |
Region or state |
|
Main ingredients | Fish |
Àdàkọ:Wikibooks-inline
|
Brudet tàbí brodet jẹ́ ọbẹ̀ ẹja èyí tí wọ́n máa ń ṣe ní ẹkùn àwọn Croatia ti Dalmatia,[1] Kvarner, àti Istria, àti pẹ̀lú àwọn etíkun Montenegro. Brodetto di pesce, tàbí ní ṣókí brodetto (broeto ní èdè Venetia, brudèt nínú ẹ̀ka èdè Romagnol, el brudèt ní Fanese, el brudettu ní Portorecanatese, lu vrëdètte ní Sambenedettese, lu vredòtte ní Giulianova dialect, u' Bredette ní Termolese, lu vrudàtte ní ẹ̀ka èdè Vastese), ó jẹ́ oúnjẹ tí ọ̀pọ̀ àwọn Italian tí wọ́n wà ní àwọn ìlú Adriatic fẹ́ràn sí,[2] Romagna,[3] Marche, Abruzzo,[4] àti Molise). Ó kún fún onírúurú ọbẹ̀ ẹja àti àwọn ohun èlò, ẹ̀fọ́, àti wáìnì pupa tàbí funfun,[5] [6] tàbí vinegar.[7] Èyí tí ó ṣe pàtàkì jùlọ́ nínú brodetto ni ọ̀nà tí ó rọrùn láti fi sè é nínú ìkòkò ìse-oúnjẹ kan. Wọ́n sáábà máa ń jẹ ẹ́ pẹ̀lú polenta tàbí búrẹ́dì, nígbà tí àwọn mìíràn máa ń jẹ ẹ́ pẹ̀lú ànàmọ́ tàbí búrẹ́dì. Brodetto lè yàtọ̀ nínú adùn, ìrísí, ó dá lórí irúfẹ́ àwọn ohun èlò ìsebẹ̀ tí wọ́n lò àti ọ̀nà tí wọ́n fi sè é.[1]
Ó jẹ́únjẹ kan láti Corfu èyí tí a mọ̀ sí bourdeto.
|url-status=
ignored (help)