Bísí Kọ́mọláfẹ́ |
---|
Ọjọ́ìbí | Bísí Kọ́mọláfẹ́ Veronica 1986 Ìbàdàn, Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ |
---|
Aláìsí | 31 December 2012 University College Hospital, Ibadan |
---|
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
---|
Iṣẹ́ | |
---|
Ìgbà iṣẹ́ | 2008–2012 |
---|
Bísí Kọ́mọláfẹ́, tí a bí ní inú ọdún 1986 jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé, olùdarí eré, olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Bísi di ìlú-mòọ́ká lẹ́yìn tí ó kópa nínú eré Ìgboro ti Dàrú àti Aramotu Igboro Ti Daru and Aramotu.[1]
Bísi ni ó jẹ́ àbílé kejì àwọ òbí rẹ̀ nínú àwọn ọmọ márùn ún tí àwọn òbí rẹ̀ bí ní ìlú Ìbàdàn ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ àti girama ní ìlú Ìbàdàn kan náà.[2] Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ Yunifásitì Ìpínlẹ̀ Èkó (LASU) níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ gboyè àkọ́kọ́ nínú Business Administration.[3][4]
Bísí bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ tí ó sì di ìlú-mòọ́ká nínú eré oníṣẹ́ nígbà tí ó kópa nínú eré Ìgboro ti dàrú, àti ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí olú ẹ̀dá ìtàn nínú eré Bólóde ò kú, Àṣírí owó, Èbúté, Ẹja tútù atu Ọká.
Bisi's acting career shot into limelight after she starred in the movie Igboro Ti Daru. She went on to play leading roles in films including Bolode O'ku, Asiri Owo and Ebute.[5] She was nominated in the "Revelation of The Year" category at the 2009 Best of Nollywood Awards and in the "Best Lead Actress in a Yoruba film" category at the 2012 edition.[6]
Bísí Kọ́mọláfẹ́ gbàgboro kan ní ọjọ́ Kọkànlélọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 2012. Ó papò dà látàrí ipò ìlóyún tí ó wà, gẹ́gẹ́ bí gbogbo àwọn Ìwé-ìròyìn ti fìdí rẹ̀ múlẹ̀. [8][9][10] Ó papò dà ní ilé ìwòsàn ìkọ́ni ti ìlúÌbàdàn tí wọ́n sì sin-ín ní ọjọ́ kẹrin oṣù Kíní ọdún 2013. [11] in Ibadan.[12]
- Igboro Ti Daru
- Aye Ore Meji
- Apere Ori
- Omo Olomo Larin Ero
- Jo Kin Jo
- Akun
- Bolode O'ku
- Aramotu
- Asiri Owo
- Ogbe Inu
- Aiyekooto
- Latonwa
- Alakada
- Mofe Jayo
- Ebute
- Iberu Bojo
Kọ́mọláfẹ́ ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú ọkọ rẹ̀ Túndé Ìjàdùnọlá tí ó fi orílẹ̀-èdè Canada ṣe ibùgbé, amọ́ tí ó jẹ́ ọmọ Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. [13]
- ↑ "Nollywood actress, Bisi Komolafe, for burial in Ibadan, tomorrow". Vanguard. 3 January 2013. http://www.vanguardngr.com/2013/01/nollywood-actress-bisi-komolafe-for-burial-in-ibadan-tomorrow/. Retrieved 25 August 2015.
- ↑ "Untold Story Of Bisi Komolafe’s Mysterious Death - She Died Of Spiritual Attack". MJ Celebrity Magazine. 2015-03-27. Archived from the original on 2015-03-27. Retrieved 2022-02-01.
- ↑ Akinnagbe Akintomide (3 January 2013). "PICTURES: THE UNTOLD STORY ABOUT THE MYSTERIOUS DEATH OF MOVIE STAR BISI KOMOLAFE". Nigeria Films. Archived from the original on 10 March 2016. Retrieved 25 August 2015.
- ↑ "Bisi Komolafe biography, net worth, age, family, contact & picture". www.manpower.com.ng. Retrieved 2020-09-30.
- ↑ Bayo Adetutu (1 January 2013). "Bisi Komolafe, Nollywood actress dies". P.M. News. http://www.pmnewsnigeria.com/2013/01/01/bisi-komolafe-nollywood-actress-dies/. Retrieved 25 August 2015.
- ↑ 6.0 6.1 "Best of Nollywood Awards 2009". BellaNaija. 7 December 2009. Retrieved 25 August 2015.
- ↑ "Best of Nollywood Awards: List of Nominees". Nollywood by Mindspace. 2014-10-15. Archived from the original on 2014-10-15. Retrieved 2022-02-01.
- ↑ Oseyiza Ogbodo (28 December 2013). "January 2013 HIGHLIGHTS: Bisi Komolafe dies". National Mirror. Archived from the original on 24 August 2014. https://web.archive.org/web/20140824094034/http://nationalmirroronline.net/new/january-2013-highlights-bisi-komolafe-dies/. Retrieved 25 August 2015.
- ↑ "Bisi Komolafe's Doctor speaks about her cause of death". Africa Spotlight. January 13, 2013. Archived from the original on 2017-01-04. https://web.archive.org/web/20170104163630/http://africanspotlight.com/2013/01/07/bisi-komolafes-doctor-speaks-about-her-cause-of-death/. Retrieved 26 August 2015.
- ↑ Ebun Sessou (12 January 2013). "Bisi Komolafe’s property tears fiancé, family apart". Vanguard. http://www.vanguardngr.com/2013/01/bisi-komolafes-property-tears-fiance-family-apart/. Retrieved 25 August 2015.
- ↑ Ola Ajayi (4 January 2013). "Tears as Bisi Komolafe goes home". Vanguard. http://www.vanguardngr.com/2013/01/tears-as-bisi-komolafe-goes-home/. Retrieved 25 August 2015.
- ↑ Akinwale Aboluwade (January 5, 2013). "Nollywood actress, Bisi Komolafe, buried amid tears". The Punch. Archived from the original on 24 September 2015. https://web.archive.org/web/20150924130824/http://www.punchng.com/news/nollywood-actress-bisi-komolafe-buried-amid/. Retrieved 25 August 2015.
- ↑ "Bisi Komolafe biography, net worth, age, family, contact & picture". www.manpower.com.ng. Retrieved 2020-09-30.
Àdàkọ:Authority control