CDQ | |
---|---|
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Sodiq Abubakar Yusuf |
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi | CDQ olowo |
Ọjọ́ìbí | 6 Oṣù Kàrún 1985 Orile, Lagos State, Nigeria |
Irú orin | |
Occupation(s) | rapper, songwriter, performer |
Instruments | Vocals |
Years active | 2008–present |
Labels | No Struggle No Success |
Associated acts |
Sodiq Abubakar Yusuf (ìbí jẹ́ May 6, 1985), ẹni tí ayé mọ sí CDQ, jẹ́ Olórin, Ọ̀kọrin tí ó jẹ́ gbajù gbajà jẹ́ ọmọ bíbí ike Nàìjíría tí ó kọ "Nọwọ́ Sókè tí Olorin Wizkid náà kópa nínú orin náà àti Ọlámide tí ì wá lábẹ Masterkraft.[1] nígbà kàn rí o maa ń lo ohun èlò orin ki ó tó sún sí orin tí jé kí ó gbà àmi ẹ̀yẹ ní ọdún 2016 ní Nigerian Music Video Awards. Lábé ilé iṣé orin No struggle, No success Entertainment, agbẹnusọ fún CDQ ti fí orin RAP sí abé ẹyà irú orin ti CDQ ń kọ, àwọn bíi Woss Wobi tí ó kọ́kọ́ bẹrẹ.[2]
Sodiq Abubakar Yusuf jẹ́ ọmọ ìlú Ìlọrin ní ìpínlè Kwara, ní orílé Èdè Nàìjíríà;[3] amò wọn bí sí Oríle tí ó wà ní ìpínlè Èkó. Leyin tí ó wà sí Èkó láti Ìlọrin ní o parí ẹ̀kó sẹ́kọ́ǹdìrì rẹ, ó tẹ̀síwájú nínú èkó rè ní ilé ìwé Fásitì tí wá ní ìlú Èkó, Lagos state university níbi tí ó ti gbọyè B.Sc ní Ikọ́nọ́míkìsi (Economics)[4]
Ọ̀kōrin CDQ yáa ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn lẹ́nu nípa fífún àwùjọ padà ati kí á máa ṣe ìrànlọ́wọ́ ní àwùjọ. Ní ìpínlè Kwara ní ó tí ṣe èyí. Bákan náà, Ọ̀korin Cdq lọ sí ààfin Ọba ìlú Ìlọrin nígbà tí ó kọ́kọ̀ wọ̀ inú ìlú náà láti lè fí tó Ọba létí nípa èrò rẹ̀ fún àwọn ọmọ sẹkọndiri tí ó wà nínú ìlú náà. Lílõ tí ó lọ, ọjọ méjì ní ó fi dúró sínú ìlú náà, láàrin ọjọ méjì yíì nàa ní Olùdarí ilé ìwé náà tí ṣe ìgbàlejò Cdq àti àwọn ẹmẹ̀wa é, tí Olùdarí ilé ẹkọ náà sì pé àwọn ilé ẹkọ náà sì ta, èyí tí àwọn ọmọ ilẹ ẹkọ náà gba ẹ̀bùn. 9 Olórin CdQ fún àwọn ọmọ náà ni ohun ìkòwé àti Aago.
Ìgbà yìí ní agbẹnusọ olórin náà pé " iṣé àgbéṣe yìí wà láti rí pé àwọn ọmọ ilé ìwé wọn kò ní ìṣòro lórí ohun tí a fí ń kọwe, tí ìpínlè náà yóò gbà àwọn ànfààní tí o sodo sínú ohun tí wọ́n fẹ ṣe.[5]
CDQ bẹ̀rẹ̀ iṣẹ orin ní ọdún 2008 nígbà náà ni o jẹ́ elégbè okorin kàn tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Dagrin kí ó tó bẹ̀rẹ̀ orin RAP ní èdè Gẹ̀ẹ́sì pẹlú M.I Abaga.[4] Ní ọdún 2013 , ó dára pọ mọ Masterkraft (producer) tí wọn sì fi òǹtẹ̀ Lu ìwé lẹyìn ìgbà tí ó gbé ipò kíní nínú ìdíje industry Nite ní oṣù kọkànlá ọdún 2012.[6] Ní ọdún 2014, ó kó orin tí àkọlé rẹ ń jẹ́ Indomie tí Ọlámide àti Davido náà wà nínú orin náà, tí o sí kán jálẹ̀ orílé èdè Nàìjíríà. Orin tí CDW kọ lábẹ Masterkraft ló gbà jáde tí ó fi di olókìkí àti pé ó jẹ́ kí wọn Yàn-án fún gbígba àmì ẹ̀yẹ Nigeria Entertainment Awards ní 2015 àti Best Street Hop Artist Ni Headies.
Ní ìfojúsọ́nà fún Album rẹ tí ó pé àkọlé rẹ ní Qukaity CDQ Archived 2022-10-24 at the Wayback Machine. tí Olórin Wizkid naaa wà nínú rẹ tí àkọlé rẹ ń jẹ́ N'owo É Sókè jẹ orin tí ó jé kí Album àwo orin náà tám kálẹ̀. Olùdarí Fídíò orin náà ni Unlimited L.A, tí ó sí gbà àmi ẹyẹ Best Afro Hip hop Video ní ọdún 2016 ní Nigeria Music Video Awards.[7][8] On 16 August 2016, he unveiled the cover art for the album[9] before it was released through General Records on 22 August to positive critical reviews.[10][11] On 11 November 2016, he launched his own record label N.S.N.S, a short-form for No Struggle No Success Entertainment.[12] On 1 Feb 2017, he dropped his first official single under the platform titled ' Say Baba ' which was produced by Jay Pizzle.[13]
Title | Year | Album |
---|---|---|
"Ogini" (featuring Runtown) |
2014 | Non-album singles |
"Indomie" (featuring Olamide) | ||
"Indomie (Remix)" (featuring Olamide and Davido) |
2015 | Quality |
"Salaro"[14] | ||
"Talosobe" | ||
"Oobi" (featuring Cayana) | ||
"Woss Wobi (Freestyle)" (with Olamide) |
Non-album single | |
"Nowo E Soke" (featuring Wizkid) |
2016 | Quality |
"First Come First Serve" | Non-album singles | |
"Make We Run?"[15] (featuring Wizkid) | ||
"Ko Funny" (featuring Davido) |
2017 | |
"Say Baba" | ||
"Say Baba (Remix)"[16] (featuring DJ Maphorisa) | ||
"Bye Bye Poverty" | ||
"Warey yo" | 2018 | |
"Gbayi"
(featuring Kiss Daniel) | ||
"Shey Normal" | ||
Flex | ||
"Aye"
(featuring Phyno and Reminisce) | ||
"Onye Eze"
(featuring Zlatan Ibile) | ||
"Jabbing" | ||
"Fine Boyz" | ||
"Ghana Must Go" | 2019 | Ibile Mugabe |
"Entertainer (featuring Davido) | ||
"Owo" | 2020 | Non-album singles |
" Kogbede" (featuring Wande Coal) | 2021 | Non-album singles |
Year | Award ceremony | Prize | Recipient/Nominated work | Result | Ref |
---|---|---|---|---|---|
2015 | 2015 Nigeria Entertainment Awards | Best New Act to Watch | Himself | Wọ́n pèé | [17] |
Best Collabo of The Year | "Best Collabo of The Year" | Wọ́n pèé | [17] | ||
The Headies 2015 | Best Street-Hop Artiste | Himself | Wọ́n pèé | ||
2016 | 2016 Nigeria Entertainment Awards | Rap Act of the Year | Wọ́n pèé | ||
Soundcity MVP Awards 2016 | Best Hip Hop Artist | Wọ́n pèé | [18] | ||
2016 Nigeria Music Video Awards | Best Afro Hip-Hop Video | "Nowo E Soke" | Gbàá | [19] | |
2017 | 2017 Ghana-Naija Showbiz Awards | Best Street-Hop Artiste | Himself | Gbàá | [20] |
Next Superstar On The Roll | Wọ́n pèé | [21] |
|url-status=
ignored (help)
|url-status=
ignored (help)
|url-status=
ignored (help)