Crystal Clarke

Crystal Clarke
Clarke nínú Ordeal by Innocence ní ọdún 2018
Ọjọ́ìbí1993/1994
New Jersey, U.S.
Orílẹ̀-èdèAmerican
Iléẹ̀kọ́ gígaRoyal Conservatoire
Iṣẹ́Actress
Ìgbà iṣẹ́2013–present

Crystal Clarke (tí a bí ní ọdún 1993 tàbí ọdún 1994)[1] jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà. Ọ̀pọ̀ mọ́ fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi Tina Argyll nínú eré BBC àti Amazon Prime tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Ordeal by Innocence (2018) àti gẹ́gẹ́ bi Georgiana Lambe nínú eré ITV àti PBS tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Sanditon (2019–).[2][3]

Wọ́n bí Clarke ní Essex County, New Jersey, sínú ìdílé àwọn òbí Caribbean;¡ wọ́n to dàgbà nínú ìlú kan náà; ìyá rẹ̀ wá láti Trinidad, bàbá rẹ̀ sì jẹ́ ọmo Guyana.[4][5] Ó ní ẹ̀gbọ́n ọkùnrin kan.[6] Clarke lọ ilé ìwé Newark Arts High School, ó sì kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní ọdún 2011.[7]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Elber, Lynn (2020-02-08). "Actor Crystal Clarke found hope in Jane Austen adaptation, 'Sanditon'". Daily Herald (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-05-03. 
  2. "ITV and Red Planet Pictures announce cast as filming commences on Jane Austen's Sanditon". Press Centre (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-03-29. 
  3. Humphreys, Georgia (31 March 2018). "TV Quickfire: Star Wars actress Crystal Clarke on her Agatha Christie TV role". The Irish News. Retrieved 2019-03-29. 
  4. "Agatha Christie star Crystal Clarke on her favourite Glasgow haunts". HeraldScotland (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-03-29. 
  5. "Rising Star Crystal Clarke on Appearing in the West End's A Woman of No Importance & Two Star Wars Movies". Broadway.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-03-29. 
  6. "Agatha Christie star Crystal Clarke on her favourite Glasgow haunts". Glasgow Times (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-05-03. 
  7. Home Page, Newark Arts High School. Accessed June 20, 2022. "Crystal Clarke: AHS 2011 in ":2"