DJ Xclusive | |
---|---|
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Rotimi Alakija |
Ọjọ́ìbí | 16 Oṣù Kẹ̀wá 1980 St Austell England |
Occupation(s) | Dj, Àlágbásílé Òrín, Ólórín álágbásílè |
Years active | Ọdún 2003–títí dí òníì |
Labels | Empire Mates Entertainment |
Rotimi Alakija (tí á bí ní ọjó kérín-dín-lógún ósù kéwáà ọdún 1980), tí òpò mò sí́ DJ Xclusive, ó jé disc jockey Nàjíríà, Álágbéjádẹ ígbásílè ọrín átì olórìn álágbásílè.[1]
England ní á tí bí Rotimi Alakija sí ówó àwón óbí Náìjíríà. Ní òdómódé, ó pádá sí Náìjíríà látì lépà èkó ní ílé èkó King's College, Ị̀lú Èkó. Rotimi Alakija pádà sí UK látì kó èkó Physics átì ìmò sáyénsì kómpútà ní Yúnífásítì Reading, ní bí tí ó tí gbá oyé ékò ílé-ìwè gígá. Ó tún pádà kó ékò ísúná ówó kómpútà ní Yúnífásítì Brunel, London.[2]
DJ Xclusive bérè ísé ójógbón disc jockey ní ódún 2003 nípà òpò ìsé sísé ní órísí ílé íjó álé, pélù Aura Mayfair, Penthouse, Funky Buddha átí Jalouse. Láàrín áwón ódún ísé rè, DJ Xclusive tí bá òrísírísí áwón òṣèrè bí Ne-Yo, Rihanna, Mario Winans, Brick and Lace, Nas àtí Fat Joe sísé pó.[3]
Ní ábálá tí ódún 2010 tí Nigeria Entertainment Awards, tí ó wáyé ní United States, DJ Xclusive gbá àmì éyé DJ tí ó dárájú ní áyé. ́ Á yán látì díjè DJ tí ó dárájù ní átúsè tí ódụ́n 2011 tí BEFFTA Awards. Ó tún sé fíìhàn ní House Party Big Brother ódún 2013.[4]
Ní ódún 2011, DJ Xclusive dí DJ ìlé Ílé fún CoolFM 96.9[5] ó sí dárápò mó Empire Mates Entertainment gégébí òsísé DJ tí Wizkid.[6]. DJ Xclusive sé ígbéjádè orín kán "I'm Xclusive" tí ólórín tí UK-Náìjíríà Mo Eazy.Àdàkọ:Cn
Dj Xclusive fé Tinuke Ogundero ní ódún 2015.[7][8] Ótún jé ábúrò si ólówó Náìjíríà Folorunsho Alakija.[9]
|style="background: #ececec; color: grey; vertical-align: middle; text-align: center; " class="table-na" | N/A
Ódún | Ákólé | Ólúdárí Ísé | Átókásí |
---|---|---|---|
2016 | Cash Only | [11] |
|url-status=
ignored (help)