David Akpode Ejoor | |
---|---|
Fáìlì:Photo of David Akpode Ejoor.jpeg | |
Chief of Army Staff | |
In office January 1971 – 29 July 1975 | |
Asíwájú | Hassan Katsina |
Arọ́pò | Theophilus Danjuma |
Commandant of the Nigerian Defence Academy | |
In office January 1969 – January 1971 | |
Asíwájú | Brig M.R. Varma |
Arọ́pò | Maj-Gen. R.A. Adebayo |
Governor of Mid-Western Region | |
In office January 1966 – August 1967 | |
Asíwájú | Dennis Osadebay |
Arọ́pò | Sean Ikemefuna |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | [1] Ovu, British Nigeria (now Delta State, Nigeria) | 10 Oṣù Kínní 1932.
Aláìsí | 10 February 2019 Lagos, Nigeria | (ọmọ ọdún 87)
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Unaffiliated |
Military service | |
Allegiance | Nigeria |
Branch/service | Nigerian Army |
Rank | Major general |
David Akpode Ejoor RCDS, PSC, (10 January 1932 – 10 February 2019) jé̩ o̩mo̩ orílè̩-èdè Nàìjíríà,ó jẹ́ olórí Agbègbè àárín-Apá ìwọ̀-oòrùn Nàìjíríà té̩lè̩ kí ó tó di Ìpínlè̩ Bendel 1976. Ejoor tún jé̩ ọ̀gá àwọn ọmọọṣẹ́ Jagunjagun Orí-ilẹ̀ Nàìjíríà (COAS) láti ọdún 1971 di 1975.
Ní ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ iṣẹ́ Ejoor, ó darí àwọn ẹ̀ṣọ́ níbi ayẹyẹ ìgbé-àsíá sóké ní òru ọjọ́ ìgbòmìnira.[2] Ejoor sọ ọ́ di mímọ̀ pé Lieutenant Colonel ìgbà náà, tí í ṣeChukwuemeka Odumegwu Ojukwu àti Ológun Yakubu Gowon wá bá òun láti sọ̀rọ̀ nípa bí wọ́n á ṣe gbìmọ̀ dìtẹ̀ lásìkò ètò ìdìbò ti ọdún 1964.[3]
[4] Ní àṣálẹ́ ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kìn-ín-ní, púpọ̀ nínú àwọn òṣìṣẹ́ yìí lọ sí patí láti lọ ṣàjọyọ̀ pẹ̀lú Brigadier Zakariya Maimalari tó ń ṣe ìgbéyàwó.[5] Lẹ́yìn náà, Ejoor padà sí ilé-ìgbafẹ́ tó wà ní Ikoyi. Ó jí ní òwúrọ̀ ọjọ́ kejì, pẹ̀lú òkú ẹni tí wọ́n jọ sùn sínú yàrá kan náà, ìyẹn Lieutenant-Colonel Abogo Largema, nínú ọ̀gbàrá ẹ̀jẹ̀, èyí tí Emmanuel Ifeajuna àti Godfrey Ezedigbo pa ní alẹ́ ọjọ́ náá.[6]
Wọ́n bí Ejoor ní ọjọ́ kẹwàá oṣù kìíní ọdún 1932 sínú ìdílé àwọn ará Urhobo ní Ovu.
Ejoor kú ní ọjọ́ kẹwàá oṣù kejì ọdún 2019.[7] Ó kú nígbà tó wà ní ọmọdún mẹ́tàdínláàádọ́rùn-ún.
|url-status=
ignored (help)