David Alechenu Bonaventure Mark | |
---|---|
Ààrẹ ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga Ọjọ́ kẹfà Oṣù kẹfà Ọdún 2007 | |
Deputy | Ike Ekweremadu |
Asíwájú | Ken Nnamani |
Constituency | Gúúsù Benue |
Ààrẹ ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà. | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga Oṣù kẹrin Ọdún 2003 | |
Gómínà Ìpínlẹ̀ Niger | |
In office Oṣù kínín 1984 – 1986 | |
Asíwájú | Awwal Ibrahim |
Arọ́pò | Garba Ali Mohammed |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Oṣù kẹrin 1948 Zungeru, Niger State[1] |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | PDP |
David Alechenu Bonaventure Mark (bíi ní Oṣù kẹrin Ọdún 1948) jẹ́ ológun tí ó ti fẹ̀hìntì àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú Ìpínlẹ̀ Benue ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin lẹ́yìn tí ó wọlé látàrí ètò ìdìbò ti oṣù kẹrin ọdún 2007 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[3] Ó jẹ́ ààrẹ ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin.[4][5]
A bí Mark si ìlú Otukpo ní ìpínlè Benue ni osù kerin odun 1948. O lo si ilé-ìwé St. Francis Catholic Practicing ko to look since ilé-ìwé àwon ologun. Léyìn náà, o tun lo kàwé ni Nigeria Defense Academy.[4] Wón so di 2nd Lieutenant ni odun 1970, wo si tun so di Captaini ni odun 1971, ótún padà di alaga Abandoned Properties implementation Committee ni iwo ilà oòrùn ni odun 1976.
Mark jé olori Ministry of Communication àti àwon èka rè: Nigerian Telecommunications Limited(NITEL) àti Nigerian Postal Service(NIPOST).
A yan Mark gégé bi ààré ilé ìgbìmò asofin àgbà ti Naijiria ní ojó kefa, osu Kefa odun 2007. [6]
David tún díje fun Senato agbègbè Benue South lekan si ni osu kerin odun 2011, a si yan fun isejoba kerin.[7] David so pe idibo àwon eniyan ni o gbé depo, o si so fún àwon olutako rè láti sisé papò láti tún Nàìjíríà se.[5]
Nígbà ti àwon ilé ìgbìmò asofin un tún òfin Nàìjíríà se, Mark so fun àwon Senato tó kù rè láti fi àwon omo Nàìjirià si wajú ara won.[8]
Léyìn ìgbà ti àwon orílè-èdè United Kingdom satako si Nàìjirià, won si so pé wón ma se idaduro si àwon iranlowo ti wón un fun Nàìjirià. Mark so pe ki wón fi iranlowo won pa mó.[9]
Ni osu kesan odun 2018, Mark ni ipinu láti díje fun ipò ááre orílè-èdè Nàìjirià, o si yan Zainab Abdulkadir Kure ati Abba Ejemni si egbe ti o ma sé idari ipolongo ìdíje rè.[10]
O feran eré idaraya golf, tennis àti Squash.[11] O je Christieni, èyà Idoma sì ni èyà rè. O ni ìyàwó merin sí marun.>[12]
Mark ni ilé àti Helicopter ati ìbi ibalesi fún Helicopter. .[13]
|url-status=
ignored (help)