Dayo Oyewusi (tí wọ́n bí ní ọdún1966) jẹ́ abábọ́ọ̀lù badimíítìnì(badminton) Nàìjíríà .[1] Ó díje ní ọdún 1994 Commonwealth Games ní Victoria, Canada.[2] Ó gbé ipò kìíní ní ọdún 1991 ní ìdíje tí wọ́n ṣe ní Kenya fún àwọn obìnrin méjì papọ̀ lẹ́ẹ̀kan náà bíi ni kan tí ẹni Kejì rẹ̀ jẹ́ Obiageli Olorunsola.
Women's singles
Year | Tournament | Opponent | Score | Result |
---|---|---|---|---|
1991 | Kenya International | Martine de Souza | 3–11, 4–11 | Àdàkọ:Silver2 Runner-up |
Women's doubles
Year | Tournament | Partner | Opponent | Score | Result |
---|---|---|---|---|---|
1991 | Mauritius International | Obiageli Olorunsola | Martine de Souza | 15–12, 8–15, 3–15 | Àdàkọ:Silver2 Runner-up |
1991 | Kenya International | Obiageli Olorunsola | Martine de Souza | 15–10, 9–15, 18–17 | Àdàkọ:Gold1 Winner |
Mixed doubles
Year | Tournament | Partner | Opponent | Score | Result |
---|---|---|---|---|---|
1991 | Mauritius International | Agarawu Tunde | Tamuno Gibson | 6–15, 5–15 | Àdàkọ:Silver2 Runner-up |
1985 | Mozambique International | Clement Ogbo | Anatoli Skripko | Àdàkọ:Silver2 Runner-up |