Bìlísì nínú Agbada jẹ́ eré 2021 ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà,Chinneylove Eze lo ko fíìmù náà ati Umanu Elijah lo 'ludari rẹ̀. Awọn oṣere fíìmù náà ni Erica Nlewedim, Linda Osifo, àti Efe Irele. Awọran ti fíìmù náà jáde ni March 2021. Fíìmù naa ni iṣafihan pàtàkì rẹ ni Oṣu Karun ọjọ ketadinlogbon, odun 2021 àti pe o jáde ni tiata ni ọjọ keji Oṣu Keje odun 2021 àti ṣii si àwọn atunyẹwo láti ọdọ àwọn alariwisi ṣugbọn o farahan bi aṣeyọri ni ọfiisi apoti. fíìmù náà ni atilẹyin áti àwọn eroja tí Hollywood.
Awọn ọdọbinrin mẹta Irene, Okikiola, àti Tomi ṣe ifọwọsowọpọ láti wa ona bi won o se mu ijakule ba Otunba Shonibare, oloselu ti ko laanu. won ni lati wa ona ti won o gba wọ inu ile re nla tí o ni aabo pupọ àti tí ko ṣee ṣe.