Diezani Alison-Madueke | |
---|---|
Diezani Alison-Madueke at the World Economic Forum on Africa in 2012 | |
Federal Minister of Transportation | |
In office 26 July 2007 – 17 December 2008 | |
Asíwájú | Precious Sekibo |
Arọ́pò | Ibrahim Bio |
Federal Minister of Mines & Steel Development | |
In office 23 December 2008 – 17 March 2010 | |
Asíwájú | Sarafa Tunji Ishola |
Arọ́pò | Musa Mohammed Sada |
Federal Minister of Petroleum Resources | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 6 April 2010 | |
Asíwájú | Rilwanu Lukman |
President of OPEC | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 27 November 2014 | |
Asíwájú | Abdourhman Atahar Al-Ahirish |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | December 6, 1960 Port Harcourt, Rivers State, Nigeria |
Diezani K. Alison-Madueke . Arabinrin Diezani di alakoso ijoba apapo fun eto Irinna oko ni ojo kerindinlogbon osu kefa 2006. Won gbe lo si Eto Alumoni ati Idagbasoke Irin ni odun 2008, Nigba to si di April 2010, O je yiyansipo bi alakoso eto Petroleum. Ni Oṣu Karun ọjọ 11, ọdun 2021, a gba $ 153 million (140 million euro) lati ọdọ Diezani Alison-Madueke. Ati 80 ti awọn ile rẹ paapaa.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |