Ebube Nwagbo | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 24 Oṣù Kejì 1983 IMO, Nigeria |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Yunifásítì Nnamdi Azikiwe |
Iṣẹ́ | Actress |
Ìgbà iṣẹ́ | 2003 - present [1] |
Notable work | Arrested by Love |
Ebube Nwagbo jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[2] Ó tún jẹ́ olùdákoòwò.[3]
Nwagbo wá láti Umuchu, ní ìjọba agbègbè Aguata Local Government Area, Ìpínlẹ̀ Anámbra, ṣùgbọ́n ó dàgbà ní ìlú Warrí, Ìpínlẹ̀ Dẹ́ltà. Ó jẹ́ ewé àkọ́já ti àwọn òbí rẹ̀. Ó kẹ́kọ̀ọ́ ìmọ̀ Ìgbéròyìn síta ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga Yunifásítì Nnamdi Azikiwe.[4]
Ó bèrè eré ṣíṣe rẹ̀ ní ọdún 2003 nígbà tó wà lọ́mọ ogún ọdún.[5]
|url-status=
ignored (help)
|url-status=
ignored (help)
|url-status=
ignored (help)
|url-status=
ignored (help)