Eniola Badmus | |
---|---|
![]() Eniola | |
Ọjọ́ìbí | Oṣù Kẹ̀sán Ọjọ́keje, Ọdún 1983 |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Ẹ̀kọ́ | Theatre Arts |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Yunifásítì ti Ìbàdàn Yunifasiti ti Ipinle Eko |
Iṣẹ́ | òṣèré |
Eniola Badmus, (tí a bí ní Oṣù Kẹ̀sán Ọjọ́keje, Ọdún 1983),[1] òṣèré fíìmù ti Ilu Nàìjíríà . [2] Arábìnrin náà bẹ́ẹ̀ sí ní òkìkí ní ọdún 2008, lẹ́hìn tí o ṣe ìfihàn nínu fiimu Jenifa . [3]
Eniola jẹ́eẹni bíbí ìlú Èkó ní Nàìjíríà. Ó ní ẹkọ ìpìlẹ̀ àti ilé-ìwé gíga ní Ìjẹ̀bú Òde[4].Ó lọ sí Yunifásítì ti Ìbàdàn ní biti ó ti kẹ́kọ̀ọ́ Theatre Arts.Ó gba oyè M.Sc nínu Ìṣòwò ní Yunifasiti ti Ipinle Eko[5].