Federal Ministry of Education

Federal Ministry of Education
Coat of arms of Nigeria
Agency overview
Jurisdiction Government of Nigeria
Headquarters Federal Secretariat Abuja
Minister responsible Professor Tahir Mamman, SAN
Website
education.gov.ng/

Àjọ Federal Ministry of Education ni ó jẹ́ ìkan lára àwọn ilé-iṣẹ́ ìjọba Federal Ministries of Nigeria tí wọ́n ń ṣe agbátẹrù fún ètò-ẹ̀kọ́ Nàìjíríà. Àjọ yí wà ní ojúlé Block 5A (8th Floor), ní Federal Secretariat Complex, Shehu Shagari Way, Central Area, P.M.B. 146, Garki, Àbújá.

Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu yan Tahir Mamman gẹ́gẹ́ bí Mínísítà fún ètò-ẹ̀kọ́ ní ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kẹjọ 2023.[1]

"Afòjúsùn wa ni láti lo ẹ̀kọ́ gẹ́gẹ̀ bí irinṣẹ́ fún ìdàgbàsókè gbogbo ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kí wọ́n lè ṣ'àwárí ara wọn, ìrónilágbára fún iṣèjọba àwa ara wa, déédé, ìgbèrú òun ìdàgbàsókè enìkọ̀ọ̀kan àti orílẹ̀-èdè wa lábẹ́ àṣẹ Elédùmarè". [2]

Àgbekalẹ̀ àjọ náà

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Gbogbo awọn àjọ ìsàlẹ yi ni wọ́n wà ni abẹ́ àjọ Federal Ministary of Education

  • Formulating a national policy on education.
  • Collecting and collating data for purposes of educational planning and financing.
  • Maintaining uniform standards of education throughout the country.
  • Controlling the quality of education in the country through the supervisory role of the Inspectorate Services Department within the Ministry.
  • Harmonizing educational policies and procedures of all the states of the federation through the instrumentality of the National Council on Education.
  • Effecting co-operation in educational matters on an international scale.
  • Developing curricula and syllabuses at the national level in conjunction with other bodies.

Ẹ̀ka rẹ̀

(NBAIS), Kaduna.

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Jubilation at Education Ministry as Adamu takes over". Nigeria. Archived from the original on 2016-03-04. Retrieved 2015-11-14. 
  2. "Home" (in en-US). FEDERAL MINISTRY OF EDUCATION. https://education.gov.ng/. 

afdulrazak JIBRIN IBRAHIM 419-$fmoedu in 1988 to date"; "A" to actually get money from you and protect yourself

Àdàkọ:Federal Ministries of Nigeria


Àdàkọ:Nigeria-gov-stub Àdàkọ:Education-stub