Figueira Cid | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Figueira Cid 18 Oṣù Kínní 1957 Lisbon, Portugal |
Orílẹ̀-èdè | Portuguese |
Iṣẹ́ | Actor, director, writer |
Ìgbà iṣẹ́ | 1983–present |
Figueira Cid (tí wọ́n bí ní 18 Oṣù Kínní, Ọdún 1957), jẹ́ òṣèrékùnrin, olùdarí eré àti olùgbéréjáde ọmọ orílẹ̀-èdè Pọ́rtúgàl.[1][2]Ó ti kópa nínu ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn fíìmù ilẹ̀ Yúróòpù àti ilẹ̀ Áfríkà. Ó gbajúmọ̀ jùlọ fún ipa rẹ̀ nínu àwọn fíìmù bíi Ministério do Tempo, Até Amanhã, Camaradas àti The masked avenger: Lagardère.[3]