Fireboy DML | |
---|---|
![]() Fireboy DML in 2019 | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Adedamola Oyinlola Adefolahan[1] |
Ọjọ́ìbí | 5 Oṣù Kejì 1996 Abeokuta, Ogun State, Nigeria |
Irú orin | Afrobeats, R&B |
Occupation(s) |
|
Years active | 2012–present |
Labels | YBNL Nation, Empire Distribution |
Associated acts | |
Website | fireboydml.com |
Adedamola Oyinlola Adefolahan (tí wọ́n bí ní 5 February 1996),[2] tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Fireboy DML, jẹ́ olórin orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tí ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọ-ẹgbẹ́ YBNL Nation, èyí tó jẹ́ ilé-iṣẹ́ tí Olamide dá sílẹ̀.[3]
The 23-year-old artist...