Florence Kíkẹ́lọmọ Àjàyí

Florence Àjàyí
Personal information
OrúkọFlorence Kíkẹ́lọmọ Àjàyí
Ọjọ́ ìbí28 Oṣù Kẹrin 1977 (1977-04-28) (ọmọ ọdún 47)
Ibi ọjọ́ibíÀkúré, Nàìjíríà
Ìga1.64 m (5 ft 5 in)
Playing positionÀàbò
Club information
Current clubPogoń Szczecin
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
Koko Queens
Rivers Angels
Jegede Babes
until 1999Pelican Stars
1999–2001Niederkirchen
2001–2004Police Machine
2004–2008Bayelsa Queens
2008–2010Tianjin Teda
2011–2012Krka Novo Mesto7(0)
2012–2013Pogoń Szczecin
2013–Dínamo Guadalajara
National team
1998–2008Ìkọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin Nàìjíríà[A–1]19(2)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals).

Florence Kíkẹ́lọmọ Àjàyí jẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin tí ó wà nínú Ìkọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin Nàìjíríà nígbà kan rí.[1] Ó ń gba bọ́ọ̀lù díje fún ìkọ̀ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin Dínamo Guadalajara ní orílẹ̀-èdè Spain alábala kejì.[2]


Kíkẹ́lọmọ bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá fún ìkọ̀ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin Nàìjíríà pẹ̀lú Kókó Queens, Rivers Angels, Jagede Babes àti Pelican Stars ní abala ìdíje kejì tí obìnrin Nàìjíríà. Ó dara pọ̀ mọ́ ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin, Niederkirchen ti orílẹ̀-èdè Germany lẹ́yìn tí ó kópa nínú àwọn Ìkọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin Nàìjíríà nínú ìdíje tí 1999 FIFA Women's World Cup. Ọdún méjì ló lò níbẹ̀. Lẹ́yìn èyí, ó padà sí Nàìjíríà, ó sìn gbá bọ́ọ̀lù jẹun fún Ìkọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin Police FC of Lagos àti Bayelsa Queen, kí ó tó tún fò fẹ̀rẹ̀ déró China, níbi tí ó ti dara pọ̀ mọ́ ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin Tianjin Teda (women) lọ́dún 2008 tí ó sìn díje nínú ìdíje àgbábuta obìnrin wọn. Lẹ́yìn ọdún mẹ́wàá, ó dara pọ̀ mọ́ ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin ZNK KrkaSlovenia, Pogoń SzczecinPoland àti Dínamo GuadalajaraSpain.[3][4][5]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. WHY KIKELOMO AJAYI WILL NEVER PLAY FOR FALCONS AGAIN
  2. Dínamo Guadalajara signs Nigerian Florence Ajayi. FFemenino.es, 20 May 2013
  3. Statistics in the Slovenian Football Association's website
  4. "Kikelomo Ajayi Signs 2 Years Deal in Poland". Archived from the original on 19 January 2013. Retrieved 26 August 2012.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. "Letnia giełda transferowa". Archived from the original on 27 March 2016. Retrieved 26 August 2012.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)