Florence Masebe | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 14 Oṣù Kọkànlá 1972 South Africa |
Orílẹ̀-èdè | South African |
Iṣẹ́ |
|
Gbajúmọ̀ fún | Muvhango |
Florence Masebe (bíi ni ọjọ́ kerìnlélógún oṣù kọkànlá ọdún 1972) jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè South Áfríkà tí ó gbajúmọ̀ fún ipá tí ó kó nínú eré Muvhango.[1][2][3] Ó gbà àmì ẹ̀yẹ òṣèré bìnrin to dára jù láti ọ̀dọ̀ Africa Movie Award nibi ayeye kẹsàn-án tí African Movie Academy Awards.