Gbénró Ajíbádé | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Gbénró Emmanuel Ajíbádé December 8th Maiduguri, Borno State, Nigeria |
Ibùgbé | Lagos, Lagos State |
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Orúkọ míràn | Gbénró Emmanuel Ajíbádé |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ | Actor, model, TV host film producer |
Ìgbà iṣẹ́ | 2008–present |
Olólùfẹ́ | Osas Ighodaro (m. 2015–2016) |
Àwọn ọmọ | 1 |
Website | Official website |
Gbénró Àjíbádé ni wọ́n bí ní ọjọ́ kẹjọ oṣù Kejìlá. Jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé,[1] olùgbéré-jáde, model àti olóòtú ètò.
Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ Makurdi International School àti Mount Saint Gabriels Secondary School. Ó jáde ilé-ẹ̀kọ́ Fásitì ti Benue State University nínú ẹ̀kọ́ Biology.[2]
Ó kópa gẹ́gẹ́ bí olú-èdá ìtàn nínú Soap Opera ti Tinsel tí ó aì tún ti kópa nínú eré a Gbomo Gbomo Express and The Wages.
Ajibade won Most Outstanding Actor/Model of the Year at the 2011 Nigerian Model Achievers Awards.
He was married to actress Osas Ighodaro, together, they have one daughter, Azariah Tiwatope Osarugue Ajibade. [3]