George Tucker | |
---|---|
Member of the U.S. House of Representatives from Virginia's 6th district | |
In office March 4, 1823 – March 3, 1825 | |
Asíwájú | Alexander Smyth |
Arọ́pò | Thomas Davenport |
Member of the U.S. House of Representatives from Virginia's 15th district | |
In office March 4, 1819 – March 3, 1823 | |
Asíwájú | William J. Lewis |
Arọ́pò | John S. Barbour |
Member of the Virginia House of Delegates from Pittsylvania County | |
In office 1815–1816 Alongside Thomas Wooding | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | St. George's Island, Bermuda | Oṣù Kẹjọ 20, 1775
Aláìsí | April 10, 1861 Albemarle County, Virginia | (ọmọ ọdún 85)
Resting place | University of Virginia Cemetery, Charlottesville, Virginia |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Democratic-Republican |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Mary Byrd Farley, Maria Carter Tucker, Louisa Thompson |
Alma mater | College of William and Mary |
Profession | author, lawyer, professor, politician |
Signature |
George Tucker (Ọjọ́ Ogún Oṣù kẹjọ Ọdún 1775 – Ọjọ́ kẹwá Oṣù kẹrin Ọdún 1861) jẹ́ amòfin ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà, oléṣèlú, olùkọ̀tàn, olùkọ̀wé, àti olùkọ́ni. Ara àwọn iṣẹ́ mọ̀ọ́kọmọ̀ọ́kà ni àkọ́kọ́ ìṣẹ̀tàn ayé amúnisìn ní Virginia àti àwọn míràn nínú iṣẹ́ àkọ́kọ́ ìṣẹ̀tàn ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ tí orílẹ̀ èdè yìí. Tucker tún ṣe àtẹ̀jáde ìgbésíayé Thomas Jefferson, àti ìtàn United States. Tucker jẹ́ ọmọ alákóso ìlú Hamilton, Bermuda àkọ́kọ́. Ó sì ṣílọ sí Virginia nígbà tí ó pé ọmọ ogún ọdún, ó kàwé ní College of William and Mary, wọ́n sì gbàá wọlé bí amòfin. Ìgbéyàwó ẹ̀ àkọ́kọ́ pàrí pẹ̀lú ikú ìyàwó rẹ̀ tí kò bímọ Mary Farley ní ọdún 1799; ó fẹ́ ìyàwó míràn, ó bí ọmọ mẹ́fa pẹ̀lú ìyàwó rẹ̀ Maria Carter, tí ó kú nígbà tí ó pé ọdún méjìdínlógójì ní ọdún 1823. Ìyàwó rẹ̀ kẹta, tí ó jẹ́ ọmọ ọgbọ̀n ọdún jẹ́ Louisa Thompson tí ó kú ní ọdún 1858. Yàtọ̀ sí iṣè amòfin ẹ, Tucker kọ àwọn ìwé ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ fún àtẹ̀jáde. Àwọn àkọ́le rẹ̀ pé oríṣiríṣi láti èrò sí ìmọ — làti ẹrú, ndibo , àti ẹ̀kọ́ sí lílọ làti ibìkan sí ibìkan, owó ọ̀ya àti ìfowópamọ́. Wọ́n yàán ní aṣojú ní ọdun 1816 sí ilé ìgbìmọ̀ Virginia House of Delegates nìgbà kan, ó tún ṣe aṣojú ní ilé ìgbìmọ United States House of Representatives lati 1819 sí 1825.