Heart of Men | |
---|---|
Fáìlì:Heart of Men CD poster.jpg Ghanaian release poster | |
Adarí | Frank Rajah Arase |
Olùgbékalẹ̀ | Frank Rajah Arase |
Àwọn òṣèré |
|
Orin | Okyeama Qouphi |
Ìyàwòrán sinimá | Adam Umar |
Ilé-iṣẹ́ fíìmù | Heroes Films Raj Films Henrikesim Multimedia Concept |
Olùpín | Henrikesim Multimedia Concept |
Orílẹ̀-èdè | Ghana Nigeria |
Èdè | English |
Heart of Men (tí wọ́n yípadà ní Nollywood sí Forbidden Fruit láti ọwọ́ Henrikesim Multimedia Concept for International distribution) jẹ́ fíìmú ti orílẹ̀-èdè Ghana tí ó jáde ní ọdún 2009. Frank Rajah Arase ni olùdarí àti aṣàgbéjáde fíìmù yìí, lára àwọn òṣèré tó kópa nínú rẹ̀ ni Majid Michel, John Dumelo, Prince David Osei àti Yvonne Nelson. Fíìmù náà gba àmì-ẹ̀yẹ márùn-ún ní Africa Movie Academy Awards ẹlẹ́ẹ̀kẹfà.
Wọ́n bu ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹnu àtẹ́ lu fíìmù yìí nítorí bí wọ́n ṣe ṣe ìgbélárugẹ ìmúra-ìhòhò àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìbáraẹnilòpọ̀ tó hàn nínú fíìmù yìí.[1][2][3] Ó gba àmì mẹ́ta nínú márùn-ún ní orí Nollywood Reinvented tí ó gbóríyìn fún àgbéjáde fíìmù yìí pẹ̀lú iṣẹ́ tó dára, orin tó dára, ibùdó ìtàn tó yàtọ̀, àmọ́ ó ní àhunpọ̀ ìtàn inú rẹ̀ ti kẹnú jù, àti pé àwọn ìfarahàn ìbálòpọ̀ nínu fíìmù náà ti pọ̀ jù.[4]
|url-status=
ignored (help)
|url-status=
ignored (help)