Ibrahim Aliyu | |
---|---|
Military Administrator of Jigawa State | |
In office 9 December 1993 – 22 August 1996 | |
Asíwájú | Ali Sa'ad Birnin-Kudu |
Arọ́pò | Rasheed Shekoni |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 5 May 1947 |
Aláìsí | 16 July 2021 (aged 74) |
Brigadier General Ibrahim Aliyu (ọjọ́ kàrún-ún oṣù kàrún-ún ọdún 1947[1][2] sí ọjọ́ kẹrin-dín-lógún oṣù keje ọdún 2021)[3] jẹ́ alákoso Ológun ti ìpínlẹ̀ Jigawa láti oṣù kejìlá odún 1993 sí oṣù kẹjọ ọdún 1996 ní àkókò ìjọba ológun ti ọ̀gá-ogun tí ń jẹ́ General Sani Abacha.[4]
Ní ọjọ́ kẹtàlá Oṣù kìíní ọdún 1996, ọ́ fi Nuhu Sanusi jẹ́ Emir ti Dutse.[5]
Lẹ́hìn ìpadàbọ̀ sí ìjọba tiwantiwa gẹ́gẹ́ bí olúṣàkóso ológun tẹ́lẹ̀ ní láti fẹ̀hìntì kúrò nínú ẹgbẹ́ ọmọ ogun. [6]
|url-status=
ignored (help)