Àdàkọ:Infobox religious biography Abu al-Fadhl Imāmuddīn Khān Barāwli Chhachhrī[1] (tí a tún mò sí Imamuddin Punjabi) (ó kú ní 1916) jé Indian ti mùsùlùmí Sunni onímò ìjìnlè tí ó se olùdásílè Jamia Miftahul Uloom.
Àwon asááju Imāmuddīn Punjabi wá láti agbègbè Brawl, Bajaur.[2] Wón ti sí lo sí Chhachh, wón sì se ibùdó won sí Kāla Noor ní agbègbè Batala ní Punjab.[3]
A bí Imāmuddīn Punjabi ní Batala, ìlú kan nínú ìpínlè Punjab[4] ní orílé-èdè India. Ó kó èkó ahādith pèlú Ahmad Ali Saharanpuri[5] tí ó sì parí èkó rè ní ilé-èkó ìbílè ti dars-e-nizami láti Darul Uloom Deoband.[6] Nígbà tí ó parí èkó rè ní ilé-èkó ìmò èsìn ti Deoband, Punjabi se ìpinnú àjosepò pèlú Fazle Rahmān Ganj Murādābādi ní Sufism.[7]
Punjabi sí lo sí Maunath Bhanjan ní 1298 AH.[8] Ó se ìdásílè Jamia Miftahul Uloom, ilé-èkó èsìn ìlú-mòóká ní ìpínlè Uttar Pradesh.[5] ní orílé-èdè India.
Punjabi pa ipò dà ní odún 1916 ní Mau nínú àpapò ìgbèríko United Provinces of Agra and Oudh.[5]
Àgbéjáde àwon ìwé ni ìwònyí:[9]