Isi ewu

Isi ewu
Alternative namesGoat's head soup, spiced goat's head
Typemeat
Place of originNigeria
Region or stateIgboland
Main ingredientsGoat's head
Àdàkọ:Wikibooks-inline 

Isi ewu jẹ́ oúnjẹ ìbílẹ̀ àwọn Ìgbò, èyí tí wọ́n fi orí ewúrẹ́ ṣe.[1]

Ó jẹ́ oúnjẹ kan tó gbajúmọ̀ láàrín àwọn [[Igbo], tí wọ́n ma ń fi bọ̀kọ̀tọ́ọ̀/ẹsẹ̀ màlúù (nkwobi) sè. Ìyàtọ̀ tó wà níbẹ̀ ni pé ẹsẹ̀ màlùú ni wọ́n fi ṣe é tí kò sì dà bí isi ewu tí wọ́n fi ẹran ewúrẹ́ sè. Àwọn ilé ìta oúnjẹ mìíràn máa ń se gbogbo orí rẹ̀ ní ẹ̀ẹ̀kan ṣoṣọ, àwọn mìíràn á sì gé e sií wẹ́wẹ́.[2]

Orí ewúrẹ́, nutmeg (kóró ehu), àlùbọ́sà, kọ́ún, epo, ewé utazi, àti ụgba jẹ́ àwọn èròjà tí wọ́n fi ń se ọbẹ̀ Isi Ewu.[3]

Wọ́n máa bọ ẹran náà títí á fi rọ̀, èyí lè pé díẹ̀ nítorí orí ewúrẹ́ yi gan-an.[4]

Àlùbọ́sà tí wọ́n ti rẹ́, ìsebẹ̀, ata àti iyọ̀ náà wà lára àwọn èròjà tí wọ́n máa fi sí inú epo, tí wọ́n sì máa fi omi, kọ́ún, àti epo sínú ìṣasùn mìíràn.[5]

Orí ewúrẹ́, wọ́n á ti ya ọpọlọ rẹ̀ sọ́rọ̀ (wọ́n sì máa gun nínú odó), nutmeg, ugba náà máa wà nínú epo náà.[6]

Lẹ́yìn tí wọ́n bá ti sè é tán, wọ́n máa rẹ́ àlùbọ́sà sí ẹ̀gbé Isi Ewu náà pẹ̀lú ewé utazi sínú abọ́.

Ìjápọ̀ mìíràn

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Edet, Laura. "Nigeria Recipes: ISI-EWU (spiced goat head)". Archived from the original on 2009-03-01. Retrieved 2009-05-20.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. "Isi Ewu (goat head) Recipe by Diana Asare". Cookpad (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-06-09. 
  3. "Isi ewu, Goat head in spicy sauce". The Pretend Chef (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-12-17. Retrieved 2022-06-09. 
  4. "Isi Ewu". Ritman Bar & Bistro (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2022-05-23. Retrieved 2022-06-09.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. "Nigerian Isi Ewu: Spicy Goat Head". All Nigerian Recipes (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-06-09. 
  6. Dobby (2015-09-20). "Isi ewu recipe - How to make isi ewu (Sauced goat head)". Dobby's Signature (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-06-09.