J. K. Amalou | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | France |
Iṣẹ́ | Film director, screenwriter, producer |
J. K. Amalou jé aṣàgbéjáde fíìmù, olùdarí àti òǹkọ̀tàn ọmọ orílẹ̀-èdè France, tó gbajúmọ̀ fún fíìmù rẹ̀ ti ọdún 2012, tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Deviation.
Ọdún | Fíìmù | Olùdarí | Aṣàgbéjáde | Òǹkọ̀tàn | Ọ̀rọ̀ |
---|---|---|---|---|---|
1995 | Belle Époque | No | Yes | No | French miniseries |
1996 | Hard Men | Yes | Yes | Yes | [1] |
2007 | The Man Who Would Be Queen | Yes | Yes | Yes | |
2012 | Deviation | Yes | Yes | Yes | [2][3][4] |
2014 | A Place in the Stars | No | No | Yes | co-written with Ita Hozaife[5] |
2015 | Assassin | Yes | Yes | Yes | [6][7][8] co-produced with Jonathan Sothcott |