Jénífà | |
---|---|
Fáìlì:Movie poster for Jenifa.jpg | |
Adarí | Muhydeen S. Ayinde |
Olùgbékalẹ̀ | Olatunji Balogun |
Àwọn òṣèré | Funke Akindele Iyabo Ojo Ronke Odusanya Eniola Badmus Mosunmola Filani Ireti Osayemi Tope Adebayo |
Orin | Fatai Izebe |
Ìyàwòrán sinimá | Moroof Fadairo |
Olóòtú | Abiodun Adeoye |
Ilé-iṣẹ́ fíìmù | Scene One Productions |
Olùpín | Olasco Films Nig. Ltd. |
Déètì àgbéjáde |
|
Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Èdè | Yoruba |
Jénífà jẹ́ fíìmù apanilẹ́rìn-ín ti ọdún 2008 láti ọwọ́ Funke Akindele. Fíìmù náà gba àmì-ẹ̀yẹ mẹ́rin ní ọdún 2009 láti ọwọ́ Africa Movie Academy Awards, bí i òṣèrébìnrin tó dára jù lọ, Best Original Soundtrack àti fíìmù ilẹ̀ Nàìjíríà tó dára jù lọ. Akindele gba àmì-ẹ̀yẹ òṣèrébìnrin tó dára jù lọ ní ayẹyẹ Africa Movie Academy Awards fún ìkópa rẹ̀ nínú fíìmù yìí.[1][2][3][4]
Fíìmù yìí jẹ́ àgbéjáde àkọ́kọ́ tó wá padà gbajúmọ̀ ní Nàìjíríà. Apá kejì rẹ̀ jáde ní ọdún 2011, wọ́n sì tún ṣe àgbéjáde eré kúkurú irú rẹ̀ ní ọdún 2014.
|url-status=
ignored (help)