John O. Agwunobi

John Agwunobi
Assistant Secretary for Health
In office
January 4, 2006 – September 4, 2007
ÀàrẹGeorge W. Bush
AsíwájúCristina Beato (Acting)
Arọ́pòJoxel García
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbíDundee, Scotland, UK
Ẹgbẹ́ olóṣèlúRepublican
RelativesAndrew Agwunobi (brother)
EducationUniversity of Jos (BS, MD)
Johns Hopkins University (MPH)
Georgetown University (MBA)
Military service
Allegiance United States
Branch/service U.S. Public Health Service
Years of service2006–2007
Rank Admiral
CommandsUnited States Public Health Service
AwardsPublic Health Service Regular Corps Ribbon

John O. Agwunobi jẹ́ ọmọ Scotland, tó sì tún tan mọ́ orílẹl-èdè Nàìjíríà, tó jẹ́ oníṣègùn àwọn ọmọdé, ó sì fìgbà kan jẹ́ adarí agbà àti alága Herbalife Nutrition.[1] Òun sì ni igbákejì ààrẹ ti Walmart, àti ààrẹ retailer health and wellness business láti ọdún 2007 wọ 2014.[2]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Admiral John O. Agwunobi". georgewbush-whitehouse.archives.gov. Retrieved 2020-05-27. 
  2. "Dr. John Agwunobi to join Wal-Mart as Senior Vice President and President for the Professional Services Division". news.walmart.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2018-07-18. Retrieved 2017-12-22.