Juliana Kanyomozi | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 27 Oṣù Kọkànlá 1980[1] Uganda |
Orílẹ̀-èdè | Ugandan |
Iṣẹ́ | Musician, actress, entertainer |
Notable credit(s) |
|
Àwọn olùbátan | Laura Kahunde (sister) |
Musical career | |
Irú orin | |
Years active | 1998–present |
Associated acts | Iryn Namubiru, Flavia Tumusiime, Kidum Kibido |
Juliana Kanyomozi jẹ́ òṣèré àti olórin[4] ni orílẹ̀ èdè Uganda.
Kanyomozi jẹ́ mọ̀lẹ́bí pẹ̀lú Ọba Rukidi IV tí ìlú Toro[5]. Bàbá rẹ̀ jẹ́ onílù, ìyá bàbà rẹ̀ sí jẹ́ olórin[6]. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Namasagali College.[7]
Kanyomozi ní obìnrin olórin àkọ́kọ́ tí ó má gba àmì ẹ̀yẹ tí Artist of the Year láti ọ̀dọ̀ Pearl of Africa Music Awards[8]. Ó bẹ̀rẹ̀ eré ṣíṣe ni ọdún 2008 pẹ̀lú eré The Movie èyí tí Henry Ssali gbé kalẹ̀.[9][10] Ní oṣù kẹta ọdún 2014, ó di àmbásẹ́dọ̀ fún Oriflame.[11] Ní ọdún 2011, wọ́n yàán fún àmì ẹ̀yẹ Pan Africa Artiste láti ọ̀dọ̀ Nigerian Entertainment Awards.[12] Ní oṣù kejìlá ọdún 2015, wọ́n fún ní Lifetime Achievement Awards láti ọ̀dọ̀ Diva Awards Africa.[13] Ó ṣe adájọ́ fún ìdíje orin Tusker Project Fame láti ọdún 2009 di 2013.[14]
Kanyomozi pàdánù ọmọ rẹ̀ ọkùnrin tí orúkọ rẹ jẹ́ Keron Raphael Kabugo ní oṣù keje ọdún 2014.[15][16] Ní ọjọ́ kejìlá oṣù karùn-ún ọdún 2020, ó bí ọmọkùnrin tí ó pè ní Raj.[17] Ní ọdún 2006, òun àti Kassim Ouma jọ jẹ́ olólùfẹ́.[18] Ní ọdún 2020, ó bí ọmọkùnrin.[19][20] Ní ọdún 2013, ìwé ìròyìn tí Big Eye Magazine sọ wí pé Kanyomozi ní obìnrin tó rẹwà jùlọ ní gbogbo orílẹ̀ èdè Uganda.[21]
Ọdún | Àmì ẹ̀yẹ | Ẹ̀kà | Èsì |
---|---|---|---|
Airtel Women of Substance Award | Music Category | Gbàá | |
HiPipo Music Awards | Best Female Afro-Beat Song – Eddiba | Gbàá[22] | |
Best Female Artist[23] | Yàán | ||
Best Artist on Social Media | Yàán | ||
Best Female Afromix Song[23] | Yàán | ||
2013 | Warid Women of Substance | Entertainment Award | Gbàá |
HiPipo Music Awards | Best Female Artist | Yàán | |
Best Artist on Social Media | Yàán | ||
Best Zouk Song | Yàán | ||
Best R&B Song | Yàán | ||
2012 | Kora Awards | Best Female Artist East Africa "I Am Ugandan" | Gbàá |
Super Talent Awards, Uganda | Most Gifted Artist | Gbàá | |
BEFFTA Awards, UK | Best International Afrobeats Act | Gbàá | |
HiPipo Charts | Best Afro Beat Act – "Sanyu Lyange" | Gbàá[24] | |
Best Video Act – "Sanyu Lyange" | Gbàá[25] | ||
Specially Appreciated Hipipo Charts Female Artist | Gbàá[26] | ||
Kisima Awards | Best East African Collaboration – "Mpita Njia" | Yàán | |
2011 | East African Music Awards | Best Female Artist – "Alive Again" | Gbàá |
Best East African Collaboration – "Haturudi Nyuma" | Yàán | ||
Diva Music Awards Uganda | Afrobeat Diva – "Sanyu Lyange" | Gbàá | |
Super Diva – "Alive Again" | Yàán | ||
Exceptional Video– "Sanyu Lyange" | Yàán | ||
Exceptional Song– "Omutima" | Yàán | ||
R&B Diva – "Libe'esanyu" | Yàán | ||
Kisima Awards | Best East African | Yàán | |
Song of The Year – "Haturudi Nyuma" | Yàán | ||
Museke Online African Music Awards New York | Best Female Artist | Yàán | |
Best Soul/R&B Artist | Yàán | ||
Best East African Act | Yàán | ||
Nigeria Entertainment Awards | Pan African Artists – "Alive Again" | Yàán | |
2010 | 2010 Tanzania music awards | Best East African Song – "Haturudi Nyuma" with Kidum | Gbàá |
Diva Awards Uganda | Best R&B Artist – "Kantambule Naawe" | Yàán | |
Africa Music Awards | Pan African Artist – "Haturudi Nyuma" | Yàán | |
Pearl of Africa Music Awards | Female Artist – "Kantambule Naawe" | Yàán | |
2009 | African Music Awards | Best Female Act, Best East African Act | Yàán |
2008 | Pearl of Africa Music Awards | Artist of the Year & Best R&B Artiste/Group & Best Female Artist | Gbàá[27][28] |
Kisima Music Awards | Ugandan Song of the Year; (a) Afrobeat Song – "Diana"; Best Collaboration – Usiende Mbali | Yàán | |
2007 | Pearl of Africa Music Awards | Best R&B Artiste/Group | Gbàá |
2007 | Teenz Awards | Female Artist – "Kibaluma" | Yàán |
2006 | Pearl of Africa Music Awards | Best R&B artist/group | Gbàá |
2006 | Tanzania Music Awards | Best Ugandan song ("mama mbire") | Gbàá |
2005 | Pearl of Africa Music Awards | Best R&B Artists & Best Female Artist & Song of the Year – "Mama Mbiire" with Bobi Wine & Best R&B Single – "Nabikoowa" | Gbàá[27][29] |
2005 | Kora Awards | Best East African Song – "All I Wanna Do | Yàán |
2004 | Pearl of Africa Music Awards | Best R&B Artists | Gbàá[27][30] |
|url-status=
ignored (help)
|url-status=
ignored (help)
|url-status=
ignored (help)
|url-status=
ignored (help)
|url-status=
ignored (help)
|url-status=
ignored (help)
|url-status=
ignored (help)
|url-status=
ignored (help)
|url-status=
ignored (help)
|url-status=
ignored (help)
|url-status=
ignored (help)
|url-status=
ignored (help)