Kanayo O. Kanayo | |
---|---|
Kanayo O. Kanayo at the Aka Ikenga dinner event in Lagos, Nigeria, 2008 | |
Ọjọ́ìbí | Anayo Modestus Onyekwere 1 Oṣù Kẹta 1962 Mbaise, Imo State, Nigeria |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Naijiria |
Iṣẹ́ | Actor |
Ìgbà iṣẹ́ | 1992- till date |
Notable work | Living in Bondage |
Anayo Modestus Onyekwere[1][2] (tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Kanayo O. Kanayo, ní wọ́n bí ní Ọjọ́ kìíní oṣù kẹta ọdún 1962 (March 1, 1962) ni ìlú Mbaise, ní Ìpínlẹ̀ Imo,lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà [3] jẹ́ gbajúgbajà òṣèré sinimá àgbéléwò ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Gbajúmọ̀ rẹ̀ lágbo òṣèré tíátà pọ̀ tó bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ tí ó fi gba àmìn ẹ̀yẹ Academy Award òṣèré sinimá àgbéléwò olú-ẹ̀dá-ìtàn tí ó dára jù lọ lọ́dún 2006.[4]
Ọdún 1992, Kanayo bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ sinimá àgbéléwò lọ́dún nínú eré kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Living in Bondage.[5] Kanayo has starred in over 100 films.[5] Ní báyìí, ó jẹ́ aṣojú àjọ àgbáyé, United Nations ó sìn tún gbà àmìn ẹ̀yẹ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, MFR.[6]