Kareem Adepoju | |
---|---|
Orúkọ míràn | Bàbá Wándé |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Naijiria |
Iṣẹ́ | òṣèré . oǹkọ̀tàn |
Notable work | Ti Oluwa Ni Ile |
Alhaji Kareem Adépọ̀jù tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ mọ̀ sí "Bàbá Wándé" jẹ́ òṣèré, oǹkọ̀tàn àti olùdarí sinimá àgbéléwò ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ìràwọ̀ rẹ̀ tàn lágbo àwọn òṣèré tíátà nígbà tí ó kópa olóyè Ọ̀tún nínú sinimá àgbéléwò kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń "Tí Olúwa Nílẹ̀".[1][2][3]