Karin Barber
Oluko litireso ni Karin Barber je ni eka-eko Ede ati Litireso Aafirika fun ojo pipe. Eka-eko yii ni o ti n sise nigba ti o n kawe oye omowe re lori litireso. 1984 ni o fi eka-eko yii sile. Ni odun 2001 o gba Ẹ̀bùn Herskovits fun ise re, The Generation of Plays: Yoruba Popular Life in Theater.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |