Kemi Lala Akindoju | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Kemi Akindoju 8 Oṣù Kẹta 1987 Ipinle Eko, Nàìjíríà |
Ẹ̀kọ́ | University of Lagos Pan African University |
Iṣẹ́ | Osere |
Ìgbà iṣẹ́ | 2005–lowolowo |
Kẹ́mi "Lala" Akindoju jẹ́ òṣèrè ọmọ Nàìjíríà kan. Ó gba ẹ̀bun Africa Magic kan fún ipa rẹ̀ nínu àṣàmùbádọ́gba fiimu Dazzling Mirage[1]
A bí Akindoju ní ọjọ́ 8 Oṣù Kẹẹ̀ta Ọdún 1987 ní ìdílé àwọn ọmọ mẹ́rin.[2] Ó jẹ́ ọmọ bíbí ìlú ondo. Ó lọ ilé-ìwé girama ti Queen's College, Ìpínlẹ̀ Èkó. Lẹ́hìn tí ó gba ìwé-ẹ̀rí tí ìdánwò West African Examinations Council (WAEC), ó tẹ̀síwájú láti kẹ́ẹ̀kọ́ nípa insurance ní Ilé-ẹ̀kọ́ gíga Yunifásitì Èkó. Ó tún gba óyè gíga láti Ilé-ẹ̀kọ́ gíga Pan-Atlantic, níbi tí ó ti kẹ́ẹ̀kọ́ media áti communication.
Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òṣèré rẹ̀ ní ọdún 2005 láti orí ìpele ṣááju kí́ ó tó lọ sińu àwọn sinimá àgbéléwò.[3]
|url-status=
ignored (help)